Alakoso Mi
-

BTV YORUBA: NI IRANTI BABA MI, IṢURA MI, ALAKOSO MI, ỌRE MI, AMUYANGAN MI
Lati Ọdọ AbdulHakeem Mutiu Adejumọ-Ajẹṣẹku, Ni Olu-ilu Naijiriya L’Abuja Baba mi, oloogbe Alhaji Mutiu Alao Adejumọ-Ajẹṣẹku, lotitọ le ti d’oloogbe, sugbọn titi laelae ni iranti yin a maa wa ninu ọkan mi. Ẹyin ni iṣura mi, ẹyin ni alakoso mi, ẹyin ni ọrẹ mi, ẹyin ni amuyangan mi. Mo mọ riri awọn ẹkọ ti ẹ… Read more